-
Sáàmù 119:144Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
144 Òdodo àwọn ìránnilétí rẹ wà títí láé.
Fún mi ní òye,+ kí n lè máa wà láàyè.
-
-
Oníwàásù 3:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Mo ti wá mọ̀ pé gbogbo ohun tí Ọlọ́run tòótọ́ ṣe máa wà títí láé. Kò sí nǹkan kan tí a máa fi kún un, kò sì sí nǹkan kan tí a máa yọ kúrò nínú rẹ̀. Ọlọ́run tòótọ́ ti ṣe é bẹ́ẹ̀ kí àwọn èèyàn lè máa bẹ̀rù rẹ̀.+
-