-
Sáàmù 119:40Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
40 Wo bí ọkàn mi ṣe ń fà sí àwọn àṣẹ rẹ.
Mú kí n máa wà láàyè nínú òdodo rẹ.
-
-
Sáàmù 119:88Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
88 Mú kí n máa wà láàyè nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀,
Kí n lè máa pa àwọn ìránnilétí tí o sọ mọ́.
-