-
2 Sámúẹ́lì 7:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, ìwọ ni Ọlọ́run tòótọ́, òtítọ́+ ni ọ̀rọ̀ rẹ, o sì ti ṣèlérí àwọn ohun rere yìí fún ìránṣẹ́ rẹ.