Sáàmù 119:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Kódà nígbà tí àwọn olórí bá jọ jókòó, tí wọ́n sì ń sọ̀rọ̀ mi láìdáa,Àwọn ìlànà rẹ ni èmi ìránṣẹ́ rẹ ń ronú lé lórí.*
23 Kódà nígbà tí àwọn olórí bá jọ jókòó, tí wọ́n sì ń sọ̀rọ̀ mi láìdáa,Àwọn ìlànà rẹ ni èmi ìránṣẹ́ rẹ ń ronú lé lórí.*