-
Sáàmù 101:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Kò sí ẹlẹ́tàn kankan tó máa gbé inú ilé mi,
Kò sì sí òpùrọ́ kankan tó máa dúró níwájú* mi.
-
-
Sáàmù 119:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Mú ọ̀nà ẹ̀tàn kúrò lọ́dọ̀ mi,+
Kí o sì fi òfin rẹ ṣojú rere sí mi.
-