Sáàmù 40:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Mo kéde ìhìn rere òdodo nínú ìjọ ńlá.+ Wò ó! Mi ò pa ẹnu mi mọ́,+Bí ìwọ náà ṣe mọ̀ dáadáa, Jèhófà.