-
Sáàmù 27:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Báyìí, orí mi yọ sókè ju àwọn ọ̀tá mi tó yí mi ká;
Màá fi igbe ayọ̀ rú àwọn ẹbọ ní àgọ́ rẹ̀;
Màá fi orin yin* Jèhófà.