Òwe 17:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àwọn ọmọ ọmọ ni adé arúgbó,Ògo àwọn ọmọkùnrin* sì ni bàbá* wọn.