ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 122:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ẹ gbàdúrà pé kí Jerúsálẹ́mù ní àlàáfíà.+

      Àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ yóò wà láìséwu, ìwọ ìlú.

  • Àìsáyà 33:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Wo Síónì, ìlú àwọn àjọyọ̀ wa!+

      Ojú rẹ máa rí Jerúsálẹ́mù bí ibùgbé tó pa rọ́rọ́,

      Àgọ́ tí wọn ò ní kó kúrò.+

      Wọn ò ní fa àwọn èèkàn àgọ́ rẹ̀ yọ láé,

      Wọn ò sì ní já ìkankan nínú àwọn okùn rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́