ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 33:8, 9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ṣe ni màá wẹ̀ wọ́n mọ́ kúrò nínú ẹ̀bi gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ tí wọ́n dá sí mi,+ màá sì dárí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn jì wọ́n àti àwọn àṣìṣe wọn.+ 9 Orúkọ ìlú yìí máa gbé mi ga, á sì mú kí wọ́n máa yìn mí, kí wọ́n sì máa fi ògo fún mi láàárín gbogbo orílẹ̀-èdè ayé tó máa gbọ́ nípa gbogbo oore tí mo ṣe fún ìlú náà.+ Ẹ̀rù á bà wọ́n, wọ́n á sì máa gbọ̀n+ nítorí gbogbo oore àti àlàáfíà tí màá mú bá ìlú náà.’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́