1 Sámúẹ́lì 20:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Nígbà náà, Dáfídì sá kúrò ní Náótì ní Rámà. Àmọ́, ó wá sọ́dọ̀ Jónátánì, ó ní: “Kí ni mo ṣe?+ Ọ̀ràn wo ni mo dá, ẹ̀ṣẹ̀ wo ni mo sì ṣẹ bàbá rẹ tí ó fi ń wá ẹ̀mí* mi?”
20 Nígbà náà, Dáfídì sá kúrò ní Náótì ní Rámà. Àmọ́, ó wá sọ́dọ̀ Jónátánì, ó ní: “Kí ni mo ṣe?+ Ọ̀ràn wo ni mo dá, ẹ̀ṣẹ̀ wo ni mo sì ṣẹ bàbá rẹ tí ó fi ń wá ẹ̀mí* mi?”