2 Sámúẹ́lì 7:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 ọba sọ fún wòlíì Nátánì+ pé: “Mò ń gbé inú ilé tí wọ́n fi igi kédárì kọ́+ nígbà tí Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wà láàárín àwọn aṣọ àgọ́.”+ 3 Nátánì dá ọba lóhùn pé: “Lọ ṣe ohunkóhun tó wà lọ́kàn rẹ, nítorí Jèhófà wà pẹ̀lú rẹ.”+
2 ọba sọ fún wòlíì Nátánì+ pé: “Mò ń gbé inú ilé tí wọ́n fi igi kédárì kọ́+ nígbà tí Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ wà láàárín àwọn aṣọ àgọ́.”+ 3 Nátánì dá ọba lóhùn pé: “Lọ ṣe ohunkóhun tó wà lọ́kàn rẹ, nítorí Jèhófà wà pẹ̀lú rẹ.”+