2 Sámúẹ́lì 5:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Hírámù+ ọba Tírè rán àwọn òjíṣẹ́ sí Dáfídì, ó kó igi kédárì + ránṣẹ́, ó tún rán àwọn oníṣẹ́ igi àti àwọn oníṣẹ́ òkúta tó ń mọ ògiri sí Dáfídì, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ilé* fún Dáfídì.+
11 Hírámù+ ọba Tírè rán àwọn òjíṣẹ́ sí Dáfídì, ó kó igi kédárì + ránṣẹ́, ó tún rán àwọn oníṣẹ́ igi àti àwọn oníṣẹ́ òkúta tó ń mọ ògiri sí Dáfídì, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ilé* fún Dáfídì.+