1 Sámúẹ́lì 17:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Dáfídì jẹ́ ọmọ Jésè ará Éfúrátà+ láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù+ ti Júdà. Jésè+ ní ọmọkùnrin mẹ́jọ,+ ó sì ti darúgbó gan-an ní ayé ìgbà Sọ́ọ̀lù.
12 Dáfídì jẹ́ ọmọ Jésè ará Éfúrátà+ láti Bẹ́tílẹ́hẹ́mù+ ti Júdà. Jésè+ ní ọmọkùnrin mẹ́jọ,+ ó sì ti darúgbó gan-an ní ayé ìgbà Sọ́ọ̀lù.