2 Sámúẹ́lì 15:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ṣùgbọ́n ọba sọ fún Sádókù pé: “Gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ pa dà sínú ìlú.+ Tí Jèhófà bá ṣojú rere sí mi, á mú mi pa dà, á tún jẹ́ kí n rí i àti ibi tó máa ń wà.+ Sáàmù 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Á sọ pé: “Èmi fúnra mi ti fi ọba mi jẹ+Lórí Síónì,+ òkè mímọ́ mi.”
25 Ṣùgbọ́n ọba sọ fún Sádókù pé: “Gbé Àpótí Ọlọ́run tòótọ́ pa dà sínú ìlú.+ Tí Jèhófà bá ṣojú rere sí mi, á mú mi pa dà, á tún jẹ́ kí n rí i àti ibi tó máa ń wà.+