36 Màá fún ọmọ rẹ̀ ní ẹ̀yà kan ṣoṣo, kí Dáfídì ìránṣẹ́ mi lè máa ṣàkóso* níwájú mi nígbà gbogbo ní Jerúsálẹ́mù,+ ìlú tí mo yàn fún ara mi láti fi orúkọ mi sí.
4 Àmọ́, nítorí Dáfídì,+ Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀ jẹ́ kí àtọmọdọ́mọ rẹ̀ máa ṣàkóso* ní Jerúsálẹ́mù,+ ó gbé ọmọ rẹ̀ dìde lẹ́yìn rẹ̀, ó sì jẹ́ kí Jerúsálẹ́mù máa wà nìṣó.