-
Òwe 27:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Òróró àti tùràrí máa ń mú ọkàn yọ̀;
Bẹ́ẹ̀ ni adùn ọ̀rẹ́ máa ń wá látinú ìmọ̀ràn àtọkànwá.+
-
9 Òróró àti tùràrí máa ń mú ọkàn yọ̀;
Bẹ́ẹ̀ ni adùn ọ̀rẹ́ máa ń wá látinú ìmọ̀ràn àtọkànwá.+