Diutarónómì 3:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Ìgbà yẹn la gba ilẹ̀ ọba àwọn Ámórì méjèèjì + tí wọ́n wà ní agbègbè Jọ́dánì, láti Àfonífojì Áánónì títí dé Òkè Hámónì+ 9 (òkè yìí ni àwọn ọmọ Sídónì máa ń pè ní Síríónì, tí àwọn Ámórì sì máa ń pè ní Sénírì), 1 Kíróníkà 5:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àtọmọdọ́mọ ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè+ gbé ilẹ̀ náà láti Báṣánì dé Baali-hámónì àti Sénírì àti Òkè Hámónì.+ Wọ́n pọ̀ gan-an.
8 “Ìgbà yẹn la gba ilẹ̀ ọba àwọn Ámórì méjèèjì + tí wọ́n wà ní agbègbè Jọ́dánì, láti Àfonífojì Áánónì títí dé Òkè Hámónì+ 9 (òkè yìí ni àwọn ọmọ Sídónì máa ń pè ní Síríónì, tí àwọn Ámórì sì máa ń pè ní Sénírì),
23 Àtọmọdọ́mọ ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè+ gbé ilẹ̀ náà láti Báṣánì dé Baali-hámónì àti Sénírì àti Òkè Hámónì.+ Wọ́n pọ̀ gan-an.