Diutarónómì 32:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Torí Jèhófà máa dá ẹjọ́ àwọn èèyàn+ rẹ̀,Ó sì máa káàánú* àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,Tó bá rí i pé okun wọn ti ń tán,Tó sì rí i pé àwọn tí kò ní olùrànlọ́wọ́ àtàwọn tó ti rẹ̀ ló ṣẹ́ kù.
36 Torí Jèhófà máa dá ẹjọ́ àwọn èèyàn+ rẹ̀,Ó sì máa káàánú* àwọn ìránṣẹ́+ rẹ̀,Tó bá rí i pé okun wọn ti ń tán,Tó sì rí i pé àwọn tí kò ní olùrànlọ́wọ́ àtàwọn tó ti rẹ̀ ló ṣẹ́ kù.