Diutarónómì 10:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Ìgbà yẹn ni Jèhófà ya ẹ̀yà Léfì sọ́tọ̀+ kí wọ́n lè máa gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà,+ kí wọ́n sì máa dúró níwájú Jèhófà, kí wọ́n lè máa ṣiṣẹ́ fún un, kí wọ́n sì máa fi orúkọ rẹ̀ súre,+ bí wọ́n ṣe ń ṣe títí dòní.
8 “Ìgbà yẹn ni Jèhófà ya ẹ̀yà Léfì sọ́tọ̀+ kí wọ́n lè máa gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà,+ kí wọ́n sì máa dúró níwájú Jèhófà, kí wọ́n lè máa ṣiṣẹ́ fún un, kí wọ́n sì máa fi orúkọ rẹ̀ súre,+ bí wọ́n ṣe ń ṣe títí dòní.