Jeremáyà 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ní àkókò yẹn, wọ́n á pe Jerúsálẹ́mù ní ìtẹ́ Jèhófà;+ gbogbo orílẹ̀-èdè á kóra jọ ní orúkọ Jèhófà sí Jerúsálẹ́mù,+ wọn kò ní ya alágídí, wọn kò sì ní ṣe ohun tí ọkàn búburú wọn sọ fún wọn mọ́.”
17 Ní àkókò yẹn, wọ́n á pe Jerúsálẹ́mù ní ìtẹ́ Jèhófà;+ gbogbo orílẹ̀-èdè á kóra jọ ní orúkọ Jèhófà sí Jerúsálẹ́mù,+ wọn kò ní ya alágídí, wọn kò sì ní ṣe ohun tí ọkàn búburú wọn sọ fún wọn mọ́.”