Jóòbù 38:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Ta ló fi ọgbọ́n sínú àwọn ìkùukùu,*+Àbí ta ló fún àwọn ohun tó wà lójú ọ̀run* ní òye?+ Òwe 3:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ọgbọ́n ni Jèhófà fi dá ayé.+ Òye ni ó fi fìdí ọ̀run múlẹ̀ gbọn-in.+ 20 Nípa ìmọ̀ rẹ̀ ni àwọn ibú omi fi pínyàTí ìkùukùu ojú sánmà sì ń mú kí ìrì sẹ̀.+
19 Ọgbọ́n ni Jèhófà fi dá ayé.+ Òye ni ó fi fìdí ọ̀run múlẹ̀ gbọn-in.+ 20 Nípa ìmọ̀ rẹ̀ ni àwọn ibú omi fi pínyàTí ìkùukùu ojú sánmà sì ń mú kí ìrì sẹ̀.+