Sáàmù 145:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ojú rẹ ni gbogbo ẹ̀dá ń wò,Ò ń fún wọn ní oúnjẹ wọn lásìkò.+ Sáàmù 147:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó ń fún àwọn ẹranko lóúnjẹ,+Àwọn ọmọ ẹyẹ ìwò tó ń kígbe fún oúnjẹ.+