Àìsáyà 24:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ayọ̀ ìlù tanboríìnì ti dáwọ́ dúró;Ariwo àwọn tó ń ṣe àríyá ti dópin;Ìró ayọ̀ háàpù ti dáwọ́ dúró.+