1 Àwọn Ọba 8:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nígbà tí àwọn àlùfáà jáde láti ibi mímọ́, ìkùukùu+ kún ilé Jèhófà.+ 11 Àwọn àlùfáà kò lè dúró ṣe iṣẹ́ wọn nítorí ìkùukùu náà, torí pé ògo Jèhófà kún ilé Jèhófà.+
10 Nígbà tí àwọn àlùfáà jáde láti ibi mímọ́, ìkùukùu+ kún ilé Jèhófà.+ 11 Àwọn àlùfáà kò lè dúró ṣe iṣẹ́ wọn nítorí ìkùukùu náà, torí pé ògo Jèhófà kún ilé Jèhófà.+