Sáàmù 44:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Agbára rẹ la ó fi lé àwọn ọ̀tá wa pa dà;+Orúkọ rẹ la ó fi tẹ àwọn tó dìde sí wa rẹ́.+