-
Jónà 1:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Àmọ́ Jónà fẹ́ lọ sí Táṣíṣì, kó lè sá fún Jèhófà. Torí náà, ó gbéra, ó lọ sí Jópà, ó sì rí ọkọ̀ òkun kan tó ń lọ sí Táṣíṣì. Ó san owó ọkọ̀, ó sì wọlé láti bá wọn lọ sí Táṣíṣì, kó lè sá fún Jèhófà.
-