Jóòbù 26:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ìhòòhò ni Isà Òkú* wà níwájú Ọlọ́run,*+Ibi ìparun* sì wà láìfi ohunkóhun bò ó. Òwe 15:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Isà Òkú* àti ibi ìparun* ṣí sílẹ̀ gbayawu lójú Jèhófà.+ Ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ ọkàn èèyàn!+