Sáàmù 63:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Mo* rọ̀ mọ́ ọ;Ọwọ́ ọ̀tún rẹ dì mí mú ṣinṣin.+ Sáàmù 73:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àmọ́ ní báyìí, ọ̀dọ̀ rẹ ni mo wà nígbà gbogbo;O ti di ọwọ́ ọ̀tún mi mú.+ Àìsáyà 41:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Torí pé èmi Jèhófà Ọlọ́run rẹ ń di ọwọ́ ọ̀tún rẹ mú,Ẹni tó ń sọ fún ọ pé, ‘Má bẹ̀rù. Màá ràn ọ́ lọ́wọ́.’+
13 Torí pé èmi Jèhófà Ọlọ́run rẹ ń di ọwọ́ ọ̀tún rẹ mú,Ẹni tó ń sọ fún ọ pé, ‘Má bẹ̀rù. Màá ràn ọ́ lọ́wọ́.’+