Jóòbù 10:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ṣebí o dà mí jáde bíi wàràTí o sì mú kí n dì bíi wàràkàṣì? 11 O fi awọ àti ẹran bò mí,O sì fi egungun àti iṣan hun mí pọ̀.+
10 Ṣebí o dà mí jáde bíi wàràTí o sì mú kí n dì bíi wàràkàṣì? 11 O fi awọ àti ẹran bò mí,O sì fi egungun àti iṣan hun mí pọ̀.+