Ẹ́kísódù 20:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “O ò gbọ́dọ̀ lo orúkọ Jèhófà Ọlọ́run rẹ lọ́nà tí kò tọ́,+ torí Jèhófà kò ní ṣàìfi ìyà jẹ ẹni tó bá lo orúkọ Rẹ̀ lọ́nà tí kò tọ́.+
7 “O ò gbọ́dọ̀ lo orúkọ Jèhófà Ọlọ́run rẹ lọ́nà tí kò tọ́,+ torí Jèhófà kò ní ṣàìfi ìyà jẹ ẹni tó bá lo orúkọ Rẹ̀ lọ́nà tí kò tọ́.+