Sáàmù 101:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Mi ò ní gbé ohun tí kò ní láárí* sí iwájú mi. Mo kórìíra iṣẹ́ àwọn tó ń yà kúrò nínú ohun tí ó tọ́;+Mi ò ní bá wọn da nǹkan kan pọ̀.*
3 Mi ò ní gbé ohun tí kò ní láárí* sí iwájú mi. Mo kórìíra iṣẹ́ àwọn tó ń yà kúrò nínú ohun tí ó tọ́;+Mi ò ní bá wọn da nǹkan kan pọ̀.*