1 Sámúẹ́lì 30:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ìdààmú bá Dáfídì gan-an, torí àwọn ọkùnrin náà ń sọ pé àwọn máa sọ ọ́ lókùúta, torí inú bí gbogbo àwọn ọkùnrin náà gan-an, nítorí àwọn ọmọkùnrin wọn àti àwọn ọmọbìnrin wọn tí wọ́n kó lọ. Àmọ́ Dáfídì fún ara rẹ̀ lókun látọ̀dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀.+
6 Ìdààmú bá Dáfídì gan-an, torí àwọn ọkùnrin náà ń sọ pé àwọn máa sọ ọ́ lókùúta, torí inú bí gbogbo àwọn ọkùnrin náà gan-an, nítorí àwọn ọmọkùnrin wọn àti àwọn ọmọbìnrin wọn tí wọ́n kó lọ. Àmọ́ Dáfídì fún ara rẹ̀ lókun látọ̀dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run rẹ̀.+