Jeremáyà 20:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ṣùgbọ́n ìwọ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, ń ṣàyẹ̀wò àwọn olódodo;Ò ń rí èrò inú* àti ọkàn.+ Jẹ́ kí n rí ẹ̀san rẹ lára wọn,+Nítorí ọwọ́ rẹ ni mo fi ẹjọ́ mi lé.+
12 Ṣùgbọ́n ìwọ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, ń ṣàyẹ̀wò àwọn olódodo;Ò ń rí èrò inú* àti ọkàn.+ Jẹ́ kí n rí ẹ̀san rẹ lára wọn,+Nítorí ọwọ́ rẹ ni mo fi ẹjọ́ mi lé.+