Sáàmù 17:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 O ti ṣàyẹ̀wò ọkàn mi, o ti bẹ̀ mí wò ní òru;+O ti yọ́ mi mọ́;+Wàá rí i pé mi ò ní èrò ibi kankan lọ́kàn,Ẹnu mi kò sì dẹ́ṣẹ̀.
3 O ti ṣàyẹ̀wò ọkàn mi, o ti bẹ̀ mí wò ní òru;+O ti yọ́ mi mọ́;+Wàá rí i pé mi ò ní èrò ibi kankan lọ́kàn,Ẹnu mi kò sì dẹ́ṣẹ̀.