Sáàmù 10:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó ń dúró níbi tó fara pa mọ́ sí bíi kìnnìún nínú ihò rẹ̀.*+ Ó ń dúró láti mú ẹni tí kò ní olùrànlọ́wọ́. Ó ń mú ẹni tí kò ní olùrànlọ́wọ́ nígbà tó bá pa àwọ̀n rẹ̀ dé.+
9 Ó ń dúró níbi tó fara pa mọ́ sí bíi kìnnìún nínú ihò rẹ̀.*+ Ó ń dúró láti mú ẹni tí kò ní olùrànlọ́wọ́. Ó ń mú ẹni tí kò ní olùrànlọ́wọ́ nígbà tó bá pa àwọ̀n rẹ̀ dé.+