Jeremáyà 18:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Jẹ́ kí a gbọ́ igbe ẹkún láti inú ilé wọnNígbà tí o bá mú àwọn jàǹdùkú* wá bá wọn lójijì. Nítorí wọ́n ti gbẹ́ kòtò láti fi mú miWọ́n sì ti dẹ pańpẹ́ fún ẹsẹ̀ mi.+
22 Jẹ́ kí a gbọ́ igbe ẹkún láti inú ilé wọnNígbà tí o bá mú àwọn jàǹdùkú* wá bá wọn lójijì. Nítorí wọ́n ti gbẹ́ kòtò láti fi mú miWọ́n sì ti dẹ pańpẹ́ fún ẹsẹ̀ mi.+