-
1 Àwọn Ọba 8:58Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
58 Kí ó mú kí ọkàn wa máa fà sí ọ̀dọ̀ rẹ̀,+ kí a lè máa rìn ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀, kí a sì máa pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́, àwọn ìlànà rẹ̀ àti àwọn ìdájọ́ rẹ̀ tí ó pa láṣẹ pé kí àwọn baba ńlá wa máa pa mọ́.
-