ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 9:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Má ṣe bá afiniṣẹ̀sín wí, torí á kórìíra rẹ.+

      Bá ọlọ́gbọ́n wí, yóò sì nífẹ̀ẹ́ rẹ.+

  • Òwe 19:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Gbá afiniṣẹ̀sín,+ kí aláìmọ̀kan lè ní àròjinlẹ̀,+

      Sì bá olóye wí, kí ìmọ̀ rẹ̀ lè pọ̀ sí i.+

  • Òwe 25:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Bíi yẹtí wúrà àti ohun ọ̀ṣọ́ tí wọ́n fi wúrà tó dára ṣe

      Ni ọlọ́gbọ́n tó ń báni wí jẹ́ ní etí ẹni tó ń gbọ́ràn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́