ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 77:5, 6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Mo rántí ìgbà àtijọ́,+

      Àwọn ọdún tó ti kọjá tipẹ́tipẹ́.

       6 Ní òru, mo rántí orin mi;*+

      Mo ṣàṣàrò nínú ọkàn mi;+

      Mo* fara balẹ̀ ṣèwádìí.

  • Sáàmù 77:11, 12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Màá rántí àwọn iṣẹ́ Jáà;

      Màá rántí àwọn iṣẹ́ àgbàyanu tí o ti ṣe tipẹ́tipẹ́.

      12 Màá ṣe àṣàrò lórí gbogbo iṣẹ́ rẹ,

      Màá sì ronú jinlẹ̀ nípa àwọn ohun tí o ṣe.+

  • Sáàmù 111:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Àwọn iṣẹ́ Jèhófà tóbi;+

      ד [Dálétì]

      Gbogbo àwọn tó fẹ́ràn wọn máa ń kẹ́kọ̀ọ́ nípa wọn.+

      ה [Híì]

       3 Àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ní ògo àti ọlá ńlá,

      ו [Wọ́ọ̀]

      Òdodo rẹ̀ sì wà títí láé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́