Sáàmù 40:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jọ̀ọ́ Jèhófà, jẹ́ kó wù ọ́ láti gbà mí sílẹ̀.+ Jèhófà, tètè wá ràn mí lọ́wọ́.+ Sáàmù 70:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àmọ́, aláìní ni mí, mi ò sì ní olùrànlọ́wọ́;+Ọlọ́run, tètè wá ràn mí lọ́wọ́.+ Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi àti olùgbàlà mi;+Jèhófà, má ṣe jẹ́ kó pẹ́.+
5 Àmọ́, aláìní ni mí, mi ò sì ní olùrànlọ́wọ́;+Ọlọ́run, tètè wá ràn mí lọ́wọ́.+ Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi àti olùgbàlà mi;+Jèhófà, má ṣe jẹ́ kó pẹ́.+