Sáàmù 27:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Má fi ojú rẹ pa mọ́ fún mi.+ Má fi ìbínú lé ìránṣẹ́ rẹ kúrò. Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi;+Má pa mí tì, má sì fi mí sílẹ̀, Ọlọ́run ìgbàlà mi.
9 Má fi ojú rẹ pa mọ́ fún mi.+ Má fi ìbínú lé ìránṣẹ́ rẹ kúrò. Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi;+Má pa mí tì, má sì fi mí sílẹ̀, Ọlọ́run ìgbàlà mi.