Sáàmù 25:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mú mi mọ àwọn ọ̀nà rẹ, Jèhófà;+Kọ́ mi ní àwọn ipa ọ̀nà rẹ.+