Sáàmù 30:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ fi orin yin* Jèhófà, ẹ̀yin ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀,+Ẹ fi ọpẹ́ fún orúkọ* mímọ́ rẹ̀;+ Hébérù 13:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ẹ jẹ́ ká máa rú ẹbọ ìyìn sí Ọlọ́run nípasẹ̀ rẹ̀ nígbà gbogbo,+ ìyẹn èso ètè wa+ tó ń kéde orúkọ rẹ̀ ní gbangba.+
4 Ẹ fi orin yin* Jèhófà, ẹ̀yin ẹni ìdúróṣinṣin rẹ̀,+Ẹ fi ọpẹ́ fún orúkọ* mímọ́ rẹ̀;+ Hébérù 13:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ẹ jẹ́ ká máa rú ẹbọ ìyìn sí Ọlọ́run nípasẹ̀ rẹ̀ nígbà gbogbo,+ ìyẹn èso ètè wa+ tó ń kéde orúkọ rẹ̀ ní gbangba.+
15 Ẹ jẹ́ ká máa rú ẹbọ ìyìn sí Ọlọ́run nípasẹ̀ rẹ̀ nígbà gbogbo,+ ìyẹn èso ètè wa+ tó ń kéde orúkọ rẹ̀ ní gbangba.+