Sáàmù 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Á sọ pé: “Èmi fúnra mi ti fi ọba mi jẹ+Lórí Síónì,+ òkè mímọ́ mi.” Sáàmù 144:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Sí Ẹni tó ń fún àwọn ọba ní ìṣẹ́gun,*+Ẹni tó ń gba Dáfídì ìránṣẹ́ rẹ̀ sílẹ̀ lọ́wọ́ idà tó ń pani.+
10 Sí Ẹni tó ń fún àwọn ọba ní ìṣẹ́gun,*+Ẹni tó ń gba Dáfídì ìránṣẹ́ rẹ̀ sílẹ̀ lọ́wọ́ idà tó ń pani.+