Ìfihàn 19:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mo sì gbọ́ ohun tó dún bí ohùn àwọn tó pọ̀ gan-an àti bí ìró omi tó pọ̀ àti bí ìró àwọn ààrá tó rinlẹ̀. Wọ́n sọ pé: “Ẹ yin Jáà,*+ torí Jèhófà* Ọlọ́run wa, Olódùmarè,+ ti bẹ̀rẹ̀ sí í jọba!+
6 Mo sì gbọ́ ohun tó dún bí ohùn àwọn tó pọ̀ gan-an àti bí ìró omi tó pọ̀ àti bí ìró àwọn ààrá tó rinlẹ̀. Wọ́n sọ pé: “Ẹ yin Jáà,*+ torí Jèhófà* Ọlọ́run wa, Olódùmarè,+ ti bẹ̀rẹ̀ sí í jọba!+