-
Ìṣe 4:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Nígbà tí wọ́n gbọ́, gbogbo wọn jọ gbé ohùn wọn sókè sí Ọlọ́run, wọ́n sọ pé:
“Olúwa Ọba Aláṣẹ, ìwọ ni Ẹni tó dá ọ̀run àti ayé àti òkun pẹ̀lú gbogbo ohun tó wà nínú wọn,+
-