26 “Ẹ gbé ojú yín sókè ọ̀run, kí ẹ sì wò ó.
Ta ló dá àwọn nǹkan yìí?+
Òun ni Ẹni tó ń mú wọn jáde bí ẹgbẹ́ ọmọ ogun ní iye-iye;
Ó ń fi orúkọ pe gbogbo wọn.+
Torí okun rẹ̀ tó fi ń ṣiṣẹ́ pọ̀ yanturu, agbára rẹ̀ sì ń bani lẹ́rù,+
Ìkankan nínú wọn ò di àwátì.