Jóòbù 37:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Nítorí ó sọ fún yìnyín pé, ‘Rọ̀ sórí ayé,’+Ó sì sọ fún ọ̀wààrà òjò pé, ‘Rọ̀ sílẹ̀ rẹpẹtẹ.’+