Jóòbù 37:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Èémí Ọlọ́run ń mú kí omi dì,+Omi tó lọ salalu sì máa ń dì gbagidi.+